[go: nahoru, domu]

Jump to content

Eku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àtúnyẹ̀wò ní 17:41, 29 Oṣù Èrèlé 2024 l'átọwọ́ 109.252.93.143 (ọ̀rọ̀)
(ìyàtọ̀) ← Àtúnyẹ̀wò tópẹ́ju | Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí (ìyàtọ̀) | Àtúnyẹ̀wò tótuntunju → (ìyàtọ̀)
Mus musculus
Eku ilé

Eku

Orisii meji lo wa, dudu ati pupa resuresu (brown). Awon eku maa n gun ni iwon insi merindinlogun ninu eyi ti insi mejo re maa n je iru. Won maa n ba nnkan je pupo ni pataki awon ti o dudu. Ni laboretiri, won maa n sin awon eku funfun kan ti won fi maa n se iwadii.